|
|
|||
|
||||
OverviewṢé ẹ fẹ́ kọ́ àwọn ọmọ yín láti ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú Jésù, kí wón sì jẹ́ kí àdúrà di àṣà ojoojúmọ́ fún wọ́n lati kékeré? Bíbá Jésù Sọ̀rọ̀ Àṣà Àdúrà Ojoojúmọ́ Fún Àwọn Ọmọdé jẹ́ ìwé Kristẹni tó lè ràn àwọn ọmọ yín lọ́wọ́, láti omo owó sí odún mewa (0 sí 10), láti kọ́ bí wón ṣe lè bá Jésù sọ̀rọ̀ ní èdè Yorùbá. Ìwé ìgbàgbọ́ yìí dára fún: àwọn ìdílé onígbàgbọ́ àwọn òbí àwọn olùkọ́ ní ilé-ìjọsìn àwọn olùkọ́ ni ilé-ìwé alakọ́bẹrẹ ..................................................................................................................................................................... Would you like to teach your kids how to talk to Jesus, and make prayer a part of their everyday life? Talking with Jesus: Making Prayer a Habit for Kids is a Christian picture book that helps children, ages 0-10, learn to pray in Yoruba language. This faith-based prayer book is perfect for Christian parents, grandparents, Sunday school teachers, and preschool storytime. Full Product DetailsAuthor: Damilola C Kadiri , Jennifer Onuegbu , Olanrewaju OlawuyiPublisher: 1nebody Publishers Imprint: 1nebody Publishers Dimensions: Width: 21.60cm , Height: 0.20cm , Length: 21.60cm Weight: 0.104kg ISBN: 9781069835130ISBN 10: 1069835137 Pages: 34 Publication Date: 20 April 2026 Recommended Age: From 0 to 10 years Format: Paperback Publisher's Status: Active Availability: Available To Order We have confirmation that this item is in stock with the supplier. It will be ordered in for you and dispatched immediately. Language: Yoruba Table of ContentsReviewsAuthor InformationTab Content 6Author Website:Countries AvailableAll regions |
||||